Amo 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati bi nwọn tilẹ lọ si igbèkun niwaju awọn ọta wọn, lati ibẹ̀ wá li emi o ti paṣẹ fun idà, on o si pa wọn: emi a si tẹ̀ oju mi mọ wọn lara fun ibi, kì isi ṣe fun ire.

Amo 9

Amo 9:1-13