Amo 9:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ẹlẹṣẹ ninu enia mi yio ti ipa idà kú, ti nwipe, Ibi na kì yio le wa ba, bẹ̃ni kì yio ba wa lojijì.

Amo 9

Amo 9:8-13