Amo 3:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin nikan ni mo mọ̀ ninu gbogbo idile aiye: nitorina emi o bẹ̀ nyin wò nitori gbogbo ẹ̀ṣẹ nyin.

Amo 3

Amo 3:1-4