Amo 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina sisá yio dẹti fun ẹni yiyara, onipá kì yio si mu ipa rẹ̀ le, bẹ̃ni alagbara kì yio le gba ara rẹ̀ là.

Amo 2

Amo 2:12-16