Amo 2:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

BAYI li Oluwa wi; nitori irekọja mẹta ti Moabu, ati nitori mẹrin, emi kì o yi iyà rẹ̀ kuro; nitori o ti sun egungun ọba Edomu di ẽrú.

Amo 2

Amo 2:1-2