A. Oni 9:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin Ṣekemu si yàn awọn enia ti o ba dè e lori òke, gbogbo awọn ti nkọja lọdọ wọn ni nwọn si njà a li ole: nwọn si sọ fun Abimeleki.

A. Oni 9

A. Oni 9:15-34