A. Oni 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ABIMELEKI ọmọ Jerubbaali si lọ si Ṣekemu sọdọ awọn arakunrin iya rẹ̀, o si bá wọn sọ̀rọ, ati gbogbo idile ile baba iya rẹ̀, wipe,

A. Oni 9

A. Oni 9:1-5