A. Oni 8:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, lojukanna ti Gideoni kú, li awọn ọmọ Israeli pada, nwọn si ṣe panṣaga tọ̀ Baalimu lọ, nwọn si fi Baaliberiti ṣe oriṣa wọn.

A. Oni 8

A. Oni 8:28-35