A. Oni 8:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun sá ti fi awọn ọmọ-alade Midiani lé nyin lọwọ, Orebu ati Seebu: kini mo si le ṣe bi nyin? Nigbana ni inu wọn tutù si i, nigbati o ti wi eyinì.

A. Oni 8

A. Oni 8:1-13