A. Oni 8:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li a si tẹ̀ ori Midiani ba niwaju awọn ọmọ Israeli, nwọn kò si gbé ori wọn soke mọ́. Ilẹ na si simi ni ogoji ọdún li ọjọ́ Gideoni.

A. Oni 8

A. Oni 8:22-35