A. Oni 8:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li awọn ọkunrin Israeli wi fun Gideoni pe, Iwọ ma ṣe olori wa, iwọ, ati ọmọ rẹ, ati ọmọ ọmọ rẹ pẹlu: nitoripe o gbà wa lọwọ awọn ara Midiani.

A. Oni 8

A. Oni 8:13-27