A. Oni 5:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ-alade Issakari wà pẹlu Debora; bi Issakari ti ri, bẹ̃ni Baraki; nwọn sure li ẹsẹ̀ lọ si afonifoji na. Ni ipadò Reubeni ni ìgbero pupọ̀ wà.

A. Oni 5

A. Oni 5:5-18