A. Oni 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Baraki lepa awọn kẹkẹ́, ati ogun na, titi dé Haroṣeti awọn orilẹ-ède: gbogbo ogun Sisera si ti oju idà ṣubu; ọkunrin kanṣoṣo kò si kù.

A. Oni 4

A. Oni 4:9-24