A. Oni 4:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) AWỌN ọmọ Israeli si tun ṣe eyiti o buru li oju OLUWA, nigbati Ehudu kú tán. OLUWA si tà wọn si ọwọ́