A. Oni 3:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si pa ìwọn ẹgba marun ọkunrin ninu awọn ara Moabu ni ìgba na, gbogbo awọn ti o sigbọnlẹ, ati gbogbo awọn akọni ọkunrin; kò sí ọkunrin kanṣoṣo ti o sálà.

A. Oni 3

A. Oni 3:25-31