A. Oni 20:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia na si dide bi ọkunrin kan, wipe, Kò sí ẹnikẹni ninu wa ti yio wọ̀ inu agọ́ rẹ̀ lọ, bẹ̃ni kò sí ẹnikẹni ti yio pada si ile rẹ̀.

A. Oni 20

A. Oni 20:1-15