A. Oni 20:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni gbogbo awọn ni o ṣubu ni ijọ́ na ninu awọn ara Benjamini jẹ́ ẹgba mejila ọkunrin o le ẹgbẹrun ti o nkọ idà; gbogbo awọn wọnyi li akọni ọkunrin.

A. Oni 20

A. Oni 20:38-48