A. Oni 20:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹgba marun ọkunrin ti a ti yàn ninu gbogbo Israeli si lọ si Gibea, ìja na si le gidigidi: ṣugbọn nwọn kò si mọ̀ pe ibi sunmọ wọn.

A. Oni 20

A. Oni 20:24-38