A. Oni 20:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Benjamini si jade si wọn lati Gibea wa ni ijọ́ keji, nwọn si pa ninu awọn ọmọ Israeli ẹgba mẹsan ọkunrin; gbogbo awọn wọnyi li o nkọ idà.

A. Oni 20

A. Oni 20:22-35