A. Oni 20:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu gbogbo awọn enia yi, a ri ẹdẹgbẹrin àṣayan ọkunrin aṣòsi; olukuluku wọn le gbọ̀n kànakana ba fọnrán owu li aitase.

A. Oni 20

A. Oni 20:6-21