A. Oni 17:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin na Mika si ní ile-oriṣa kan, o si ṣe efodu, ati terafimu, o si yà ọkan ninu awọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin sọtọ̀, ẹniti o si wa di alufa rẹ̀.

A. Oni 17

A. Oni 17:1-9