A. Oni 15:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin Juda si wipe, Nitori kili ẹnyin ṣe gòke tọ̀ wa wá? Nwọn si dahùn wipe, Lati dè Samsoni li awa ṣe wá, lati ṣe si i gẹgẹ bi on ti ṣe si wa.

A. Oni 15

A. Oni 15:8-19