A. Oni 14:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn baba ati iya rẹ̀ kò mọ̀ pe ati ọwọ́ OLUWA wá ni, nitoripe on nwá ọ̀na lati bá awọn Filistini jà. Nitoripe li akokò na awọn Filistini li alaṣẹ ni Israeli.

A. Oni 14

A. Oni 14:1-11