A. Oni 13:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si gbọ ohùn Manoa; angeli Ọlọrun na si tun tọ̀ obinrin na wá, bi on ti joko ninu oko; ṣugbọn Manoa ọkọ rẹ̀ kò sí nibẹ̀ pẹlu rẹ̀.

A. Oni 13

A. Oni 13:1-14