A. Oni 12:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jefta si wi fun wọn pe, Emi ati awọn enia mi ti mbá awọn ọmọ Ammoni jà gidigidi; nigbati emi kepè nyin, ẹnyin kò si gbà mi li ọwọ́ wọn.

A. Oni 12

A. Oni 12:1-12