A. Oni 10:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn ọmọ Ammoni kó ara wọn jọ nwọn si dó si Gileadi. Awọn ọmọ Israeli si kó ara wọn jọ, nwọn si dó si Mispa.

A. Oni 10

A. Oni 10:8-18