A. Oni 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Juda si gòke lọ; OLUWA si fi awọn ara Kenaani ati awọn Perissi lé wọn lọwọ: nwọn si pa ẹgbarun ọkunrin ninu wọn ni Beseki.

A. Oni 1

A. Oni 1:3-11