A. Oni 1:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sebuluni kò lé awọn ara Kitroni jade, tabi awọn ara Nahalolu; ṣugbọn awọn ara Kenaani ngbé ãrin wọn, nwọn si nsìn.

A. Oni 1

A. Oni 1:26-34