A. Oni 1:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi ọ̀na atiwọ̀ ilu na hàn wọn, nwọn si fi oju idà kọlù ilu na; ṣugbọn nwọn jọwọ ọkunrin na ati gbogbo awọn ara ile rẹ̀ lọwọ lọ.

A. Oni 1

A. Oni 1:24-34