A. Oni 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wà pẹlu Juda; o si gbà ilẹ òke; nitori on kò le lé awọn enia ti o wà ni pẹtẹlẹ̀ jade, nitoriti nwọn ní kẹkẹ́ irin.

A. Oni 1

A. Oni 1:16-29