Titu 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ẹni tí ó wà lọ́dọ̀ mi ní kí n kí ọ. Bá wa kí gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ wa ninu igbagbọ.Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹlu gbogbo yín.

Titu 3

Titu 3:11-15