Timoti Kinni 6:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun yóo mú ìfihàn yìí wá ní àkókò tí ó bá wù ú, òun ni aláṣẹ kanṣoṣo, Ọba àwọn ọba ati Oluwa àwọn oluwa;

Timoti Kinni 6

Timoti Kinni 6:6-16