Timoti Kinni 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ìwọ eniyan Ọlọrun, sá fún nǹkan wọnyi. Máa lépa òdodo, ati ìfọkànsìn Ọlọrun, igbagbọ, ìfẹ́, ìfaradà, ati ìwà pẹ̀lẹ́.

Timoti Kinni 6

Timoti Kinni 6:3-13