Timoti Kinni 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Má kọ orúkọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀ bí opó àfi ẹni tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò bá dín ní ọgọta ọdún, tí ó sì jẹ́ aya ọkọ kan,

Timoti Kinni 5

Timoti Kinni 5:5-15