Timoti Kinni 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ìwé Mímọ́ sọ pé, “Má ṣe dí mààlúù tí ó ń tẹ ọkà lẹ́nu.” Ati pé, “Owó oṣù òṣìṣẹ́ tọ́ sí i.”

Timoti Kinni 5

Timoti Kinni 5:9-19