Timoti Kinni 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí tí a fi ń ṣe làálàá nìyí, tí a sì ń jìjàkadì, nítorí a gbẹ́kẹ̀lé Ọlọrun alààyè, ẹni tí ó jẹ́ Olùgbàlà gbogbo eniyan, pàápàá jùlọ ti àwọn onigbagbọ.

Timoti Kinni 4

Timoti Kinni 4:2-12