Timoti Kinni 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ó jẹ́ ẹni tí ó ní ẹ̀rí rere lọ́dọ̀ àwọn tí kì í ṣe onigbagbọ, kí ó má baà bọ̀ sinu ẹ̀gàn, kí tàkúté Satani má baà mú un.

Timoti Kinni 3

Timoti Kinni 3:1-16