Timoti Kinni 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀mùtí, tabi ẹni tí máa ń lu eniyan. Ṣugbọn kí ó jẹ́ onífaradà. Kò gbọdọ̀ jẹ́ alásọ̀, tabi ẹni tí ó ní ọ̀kánjúwà owó.

Timoti Kinni 3

Timoti Kinni 3:1-5