Timoti Kinni 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí bí mo bá pẹ́ kí n tó wá, kí o lè mọ̀ bí ó ti yẹ láti darí ètò ilé Ọlọrun, èyí tíí ṣe ìjọ Ọlọrun alààyè, òpó ati ààbò òtítọ́.

Timoti Kinni 3

Timoti Kinni 3:9-16