Timoti Kinni 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò gbà fún obinrin láti jẹ́ olùkọ́ni tabi láti ní àṣẹ lórí ọkunrin. Kí obinrin máa panumọ́ ni.

Timoti Kinni 2

Timoti Kinni 2:11-15