Timoti Kinni 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí tí mo fi pa àṣẹ yìí ni láti ta ìfẹ́ àtọkànwá jí ninu rẹ, pẹlu ẹ̀rí ọkàn rere ati igbagbọ tí kò lẹ́tàn.

Timoti Kinni 1

Timoti Kinni 1:1-9