Timoti Kinni 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mò ń lọ sí Masedonia, mo gbà ọ́ níyànjú pé kí o dúró ní Efesu, kí o pàṣẹ fún àwọn kan kí wọn má ṣe kọ́ eniyan ní ẹ̀kọ́ tí ń ṣini lọ́nà,

Timoti Kinni 1

Timoti Kinni 1:2-8