Timoti Kinni 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí o fi igbagbọ ati ẹ̀rí-ọkàn rere jà. Àwọn nǹkan wọnyi ni àwọn mìíràn kọ̀, tí ọkọ̀ ìgbé-ayé igbagbọ wọn fi rì.

Timoti Kinni 1

Timoti Kinni 1:10-20