Timoti Kinni 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ọlá ati ògo jẹ́ ti Ọba ayérayé, Ọba àìkú, Ọba àìrí, Ọlọrun kan ṣoṣo, lae ati laelae. Amin.

Timoti Kinni 1

Timoti Kinni 1:12-20