Timoti Keji 4:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Sa ipá rẹ láti wá kí ó tó di àkókò òtútù.Yubulọsi kí ọ, ati Pudẹsi, Linọsi, Kilaudia ati gbogbo àwọn arakunrin.

22. Kí Oluwa wà pẹlu ẹ̀mí rẹ.Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹlu gbogbo yín.

Timoti Keji 4