Timoti Keji 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa yóo yọ mí kúrò ninu iṣẹ́ burúkú gbogbo, yóo sì gbà mí sinu ìjọba rẹ̀ ní ọ̀run. Tirẹ̀ ni ògo lae ati laelae. Amin.

Timoti Keji 4

Timoti Keji 4:15-22