Timoti Keji 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí o bá ń bọ̀, bá mi mú agbádá tí mo fi sọ́dọ̀ Kapu ní Tiroasi bọ̀. Bá mi mú àwọn ìwé mi náà bọ̀, pataki jùlọ àwọn ìwé aláwọ mi.

Timoti Keji 4

Timoti Keji 4:8-21