Timoti Keji 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọn kò lè máa bá irú ìwà bẹ́ẹ̀ lọ pẹ́ títí. Nítorí pé ìwà wèrè wọn yóo hàn kedere sí gbogbo eniyan, gẹ́gẹ́ bí ti Janesi ati Jamberesi ti hàn.

Timoti Keji 3

Timoti Keji 3:8-12