Timoti Keji 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, ìwọ ní tìrẹ, dúró gbọningbọnin ninu àwọn ohun tí o ti kọ́, tí ó sì dá ọ lójú. Ranti ọ̀dọ̀ àwọn ẹni tí o ti kọ́ wọn.

Timoti Keji 3

Timoti Keji 3:8-17