Timoti Keji 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo ṣe inúnibíni sí gbogbo ẹni tí ó bá fẹ́ gbé ìgbé-ayé olùfọkànsìn gẹ́gẹ́ bí onigbagbọ. Inúnibíni níláti dé sí wọn.

Timoti Keji 3

Timoti Keji 3:9-17